ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 66:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ẹ máa rí èyí, inú yín sì máa dùn,

      Egungun yín máa yọ dáadáa bíi koríko tútù.

      Àwọn ìránṣẹ́ Jèhófà máa wá mọ ọwọ́* rẹ̀,

      Àmọ́ ó máa dá àwọn ọ̀tá rẹ̀ lẹ́bi.”+

  • Sefanáyà 3:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Kígbe ayọ̀, ìwọ ọmọbìnrin Síónì!

      Kígbe ìṣẹ́gun, ìwọ Ísírẹ́lì!+

      Máa yọ̀, sì jẹ́ kí ayọ̀ kún inú ọkàn rẹ, ìwọ ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù!+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́