-
Jòhánù 10:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Nígbà tí alágbàṣe tí kì í ṣe olùṣọ́ àgùntàn, tí kì í sì í ṣe òun ló ni àwọn àgùntàn, rí ìkookò tó ń bọ̀, ó pa àwọn àgùntàn tì, ó sì sá lọ—ìkookò gbá wọn mú, ó sì tú wọn ká—
-