-
Sekaráyà 1:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Mo bi í pé: “Kí ni àwọn yìí ń bọ̀ wá ṣe?”
Ó sọ pé: “Àwọn ìwo yìí ló fọ́n Júdà ká débi tí kò fi sí ẹnì kankan tó lè gbé orí sókè. Àwọn yìí ní tiwọn yóò wá láti dẹ́rù bà wọ́n, kí wọ́n lè ṣẹ́ ìwo àwọn orílẹ̀-èdè tó gbé ìwo wọn sókè sí ilẹ̀ Júdà, láti fọ́n ọn ká.”
-