Málákì 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “‘Ẹ̀ ń fi oúnjẹ* ẹlẹ́gbin rúbọ lórí pẹpẹ mi.’ “‘Ẹ sì sọ pé: “Kí la ṣe tí a fi sọ ẹ́ di ẹlẹ́gbin?”’ “‘Ẹ̀ ń sọ pé: “Tábìlì Jèhófà+ kò wúlò.”
7 “‘Ẹ̀ ń fi oúnjẹ* ẹlẹ́gbin rúbọ lórí pẹpẹ mi.’ “‘Ẹ sì sọ pé: “Kí la ṣe tí a fi sọ ẹ́ di ẹlẹ́gbin?”’ “‘Ẹ̀ ń sọ pé: “Tábìlì Jèhófà+ kò wúlò.”