Nehemáyà 13:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ọlọ́run mi, jọ̀wọ́ rántí wọn, nítorí wọ́n ti kó àbààwọ́n bá iṣẹ́ àlùfáà àti májẹ̀mú iṣẹ́ àlùfáà+ àti ti àwọn ọmọ Léfì.+
29 Ọlọ́run mi, jọ̀wọ́ rántí wọn, nítorí wọ́n ti kó àbààwọ́n bá iṣẹ́ àlùfáà àti májẹ̀mú iṣẹ́ àlùfáà+ àti ti àwọn ọmọ Léfì.+