Málákì 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Ṣebí bàbá kan ni gbogbo wa ní?+ Àbí Ọlọ́run kan náà kọ́ ló dá wa? Kí ló wá dé tí a fi ń dalẹ̀ ara wa,+ tí a sì ń pẹ̀gàn májẹ̀mú àwọn baba ńlá wa?
10 “Ṣebí bàbá kan ni gbogbo wa ní?+ Àbí Ọlọ́run kan náà kọ́ ló dá wa? Kí ló wá dé tí a fi ń dalẹ̀ ara wa,+ tí a sì ń pẹ̀gàn májẹ̀mú àwọn baba ńlá wa?