ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìsíkíẹ́lì 22:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Àwọn àlùfáà rẹ̀ ti rú òfin mi,+ wọ́n sì ń sọ àwọn ibi mímọ́ mi di aláìmọ́.+ Wọn ò fi ìyàtọ̀ sáàárín ohun tó mọ́ àti ohun yẹpẹrẹ,+ wọn ò jẹ́ kí àwọn èèyàn mọ ìyàtọ̀ láàárín ohun tí kò mọ́ àti ohun tó mọ́,+ wọ́n sì kọ̀ láti pa àwọn sábáàtì mi mọ́, wọ́n sì ń pẹ̀gàn mi láàárín wọn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́