Ẹ́kísódù 20:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ,+ kí ẹ̀mí rẹ lè gùn lórí ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa fún ọ.+