-
Rúùtù 4:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Lẹ́yìn náà, Bóásì fẹ́ Rúùtù, ó sì di ìyàwó rẹ̀. Ó bá a ní àṣepọ̀, Jèhófà jẹ́ kó lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kan.