Mátíù 13:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Èṣù sì ni ọ̀tá tó gbìn wọ́n. Ìparí ètò àwọn nǹkan* ni ìgbà ìkórè, àwọn áńgẹ́lì sì ni olùkórè. Mátíù 13:49 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 Bó ṣe máa rí ní ìparí ètò àwọn nǹkan* nìyẹn. Àwọn áńgẹ́lì máa jáde lọ, wọ́n á ya àwọn ẹni burúkú sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn olódodo, Mátíù 24:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nígbà tó jókòó sórí Òkè Ólífì, àwọn ọmọ ẹ̀yìn wá bá a ní òun nìkan, wọ́n sọ pé: “Sọ fún wa, ìgbà wo ni àwọn nǹkan yìí máa ṣẹlẹ̀, kí ló sì máa jẹ́ àmì pé o ti wà níhìn-ín*+ àti ti ìparí ètò àwọn nǹkan?”*+
49 Bó ṣe máa rí ní ìparí ètò àwọn nǹkan* nìyẹn. Àwọn áńgẹ́lì máa jáde lọ, wọ́n á ya àwọn ẹni burúkú sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn olódodo,
3 Nígbà tó jókòó sórí Òkè Ólífì, àwọn ọmọ ẹ̀yìn wá bá a ní òun nìkan, wọ́n sọ pé: “Sọ fún wa, ìgbà wo ni àwọn nǹkan yìí máa ṣẹlẹ̀, kí ló sì máa jẹ́ àmì pé o ti wà níhìn-ín*+ àti ti ìparí ètò àwọn nǹkan?”*+