1 Tímótì 6:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àmọ́, ìwọ tí o jẹ́ èèyàn Ọlọ́run, sá fún àwọn nǹkan yìí. Ṣùgbọ́n máa wá òdodo, ìfọkànsin Ọlọ́run, ìgbàgbọ́, ìfẹ́, ìfaradà àti ìwà tútù.+ Títù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 kí wọ́n má sọ̀rọ̀ ẹnì kankan láìdáa, kí wọ́n má ṣe jẹ́ oníjà, kí wọ́n máa fòye báni lò,+ kí wọ́n jẹ́ oníwà tútù sí gbogbo èèyàn.+
11 Àmọ́, ìwọ tí o jẹ́ èèyàn Ọlọ́run, sá fún àwọn nǹkan yìí. Ṣùgbọ́n máa wá òdodo, ìfọkànsin Ọlọ́run, ìgbàgbọ́, ìfẹ́, ìfaradà àti ìwà tútù.+
2 kí wọ́n má sọ̀rọ̀ ẹnì kankan láìdáa, kí wọ́n má ṣe jẹ́ oníjà, kí wọ́n máa fòye báni lò,+ kí wọ́n jẹ́ oníwà tútù sí gbogbo èèyàn.+