Jòhánù 8:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 12 Jésù tún sọ fún wọn pé: “Èmi ni ìmọ́lẹ̀ ayé.+ Ó dájú pé ẹnikẹ́ni tó bá ń tẹ̀ lé mi kò ní rìn nínú òkùnkùn, àmọ́ ó máa ní ìmọ́lẹ̀+ ìyè.” Jòhánù 12:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Nígbà tí ẹ ṣì ní ìmọ́lẹ̀, ẹ ní ìgbàgbọ́ nínú ìmọ́lẹ̀ náà, kí ẹ lè di ọmọ ìmọ́lẹ̀.”+ Jésù sọ àwọn nǹkan yìí, ó kúrò níbẹ̀, ó sì lọ fara pa mọ́ fún wọn. Fílípì 2:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 kí ẹ lè jẹ́ aláìlẹ́bi àti ọlọ́wọ́ mímọ́, ọmọ Ọlọ́run+ tí kò ní àbààwọ́n láàárín ìran onímàgòmágó àti oníwà ìbàjẹ́,+ láàárín àwọn tí ẹ ti ń tàn bí ìmọ́lẹ̀ nínú ayé,+
8 12 Jésù tún sọ fún wọn pé: “Èmi ni ìmọ́lẹ̀ ayé.+ Ó dájú pé ẹnikẹ́ni tó bá ń tẹ̀ lé mi kò ní rìn nínú òkùnkùn, àmọ́ ó máa ní ìmọ́lẹ̀+ ìyè.”
36 Nígbà tí ẹ ṣì ní ìmọ́lẹ̀, ẹ ní ìgbàgbọ́ nínú ìmọ́lẹ̀ náà, kí ẹ lè di ọmọ ìmọ́lẹ̀.”+ Jésù sọ àwọn nǹkan yìí, ó kúrò níbẹ̀, ó sì lọ fara pa mọ́ fún wọn.
15 kí ẹ lè jẹ́ aláìlẹ́bi àti ọlọ́wọ́ mímọ́, ọmọ Ọlọ́run+ tí kò ní àbààwọ́n láàárín ìran onímàgòmágó àti oníwà ìbàjẹ́,+ láàárín àwọn tí ẹ ti ń tàn bí ìmọ́lẹ̀ nínú ayé,+