Léfítíkù 19:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “‘O ò gbọ́dọ̀ gbẹ̀san+ tàbí kí o di ọmọ àwọn èèyàn rẹ sínú, o sì gbọ́dọ̀ nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.+ Èmi ni Jèhófà. Máàkù 12:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ìkejì ni, ‘Kí o nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.’+ Kò sí àṣẹ míì tó tóbi ju àwọn yìí lọ.”
18 “‘O ò gbọ́dọ̀ gbẹ̀san+ tàbí kí o di ọmọ àwọn èèyàn rẹ sínú, o sì gbọ́dọ̀ nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.+ Èmi ni Jèhófà.