-
Lúùkù 18:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Farisí náà dúró, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbàdúrà, ó ń dá sọ àwọn nǹkan yìí pé, ‘Ọlọ́run, mo dúpẹ́ pé mi ò dà bíi gbogbo àwọn èèyàn yòókù, àwọn tó ń fipá gba tọwọ́ àwọn èèyàn, àwọn aláìṣòdodo, àwọn alágbèrè, kódà mi ò dà bí agbowó orí yìí.
-