-
2 Àwọn Ọba 15:38Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 Níkẹyìn, Jótámù sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀, wọ́n sì sin ín pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀ sí Ìlú Dáfídì baba ńlá rẹ̀. Áhásì ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.
-