2 Àwọn Ọba 18:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ní ọdún kẹta Hóṣéà+ ọmọ Élà ọba Ísírẹ́lì, Hẹsikáyà+ ọmọ Áhásì+ ọba Júdà di ọba.