2 Àwọn Ọba 20:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Níkẹyìn, Hẹsikáyà sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀;+ Mánásè+ ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.+