Jòhánù 4:53 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 53 Bàbá náà wá mọ̀ pé wákàtí yẹn gangan ni Jésù sọ fún òun pé: “Ọmọ rẹ ti yè.”+ Torí náà, òun àti gbogbo agbo ilé rẹ̀ gbà á gbọ́.
53 Bàbá náà wá mọ̀ pé wákàtí yẹn gangan ni Jésù sọ fún òun pé: “Ọmọ rẹ ti yè.”+ Torí náà, òun àti gbogbo agbo ilé rẹ̀ gbà á gbọ́.