Jẹ́nẹ́sísì 25:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Lẹ́yìn náà, àbúrò rẹ̀ jáde, ó sì di gìgísẹ̀ Ísọ̀+ mú, torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Jékọ́bù.*+ Ẹni ọgọ́ta (60) ọdún ni Ísákì nígbà tí Rèbékà bí àwọn ọmọ náà. 1 Kíróníkà 1:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ábúráhámù bí Ísákì. Àwọn ọmọ Ísákì+ ni Ísọ̀+ àti Ísírẹ́lì.+
26 Lẹ́yìn náà, àbúrò rẹ̀ jáde, ó sì di gìgísẹ̀ Ísọ̀+ mú, torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Jékọ́bù.*+ Ẹni ọgọ́ta (60) ọdún ni Ísákì nígbà tí Rèbékà bí àwọn ọmọ náà.