Máàkù 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Bó ṣe ń rìn lọ létí Òkun Gálílì, ó rí Símónì àti Áńdérù+ arákùnrin Símónì, tí wọ́n ń ju àwọ̀n wọn sínú òkun,+ torí apẹja ni wọ́n.+ Jòhánù 1:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Áńdérù+ arákùnrin Símónì Pétérù wà lára àwọn méjì tó gbọ́ ohun tí Jòhánù sọ, tí wọ́n sì tẹ̀ lé Jésù.
16 Bó ṣe ń rìn lọ létí Òkun Gálílì, ó rí Símónì àti Áńdérù+ arákùnrin Símónì, tí wọ́n ń ju àwọ̀n wọn sínú òkun,+ torí apẹja ni wọ́n.+
40 Áńdérù+ arákùnrin Símónì Pétérù wà lára àwọn méjì tó gbọ́ ohun tí Jòhánù sọ, tí wọ́n sì tẹ̀ lé Jésù.