Lúùkù 7:34, 35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ọmọ èèyàn wá, ó ń jẹ, ó sì ń mu, àmọ́ ẹ sọ pé: ‘Wò ó! Ọkùnrin alájẹkì, ti kò mọ̀ ju kó mu wáìnì lọ, ọ̀rẹ́ àwọn agbowó orí àti àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀!’+ 35 Síbẹ̀ náà, a fi ọgbọ́n hàn ní olódodo* nípasẹ̀ gbogbo àwọn ọmọ rẹ̀.”*+
34 Ọmọ èèyàn wá, ó ń jẹ, ó sì ń mu, àmọ́ ẹ sọ pé: ‘Wò ó! Ọkùnrin alájẹkì, ti kò mọ̀ ju kó mu wáìnì lọ, ọ̀rẹ́ àwọn agbowó orí àti àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀!’+ 35 Síbẹ̀ náà, a fi ọgbọ́n hàn ní olódodo* nípasẹ̀ gbogbo àwọn ọmọ rẹ̀.”*+