ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 29:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Torí náà, èmi ni Ẹni tó tún máa ṣe àwọn ohun àgbàyanu sí àwọn èèyàn yìí,+

      Ohun àgbàyanu kan tẹ̀ lé òmíràn;

      Ọgbọ́n àwọn ọlọ́gbọ́n wọn máa ṣègbé,

      Òye àwọn olóye wọn sì máa fara pa mọ́.”+

  • Mátíù 13:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Torí ọkàn àwọn èèyàn yìí ti yigbì, wọ́n sì ti fi etí wọn gbọ́, àmọ́ wọn ò dáhùn, wọ́n ti di ojú wọn, kí wọ́n má bàa fi ojú wọn ríran láé, kí wọ́n má sì fi etí wọn gbọ́, kó má sì yé wọn nínú ọkàn wọn, kí wọ́n lè yí pa dà, kí n sì mú wọn lára dá.’+

  • Lúùkù 10:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Ní wákàtí yẹn gan-an, ó yọ̀ gidigidi nínú ẹ̀mí mímọ́, ó sì sọ pé: “Baba, Olúwa ọ̀run àti ayé, mo yìn ọ́ ní gbangba, torí pé o rọra fi àwọn nǹkan yìí pa mọ́ fún àwọn ọlọ́gbọ́n àti àwọn amòye,+ o sì ti ṣí wọn payá fún àwọn ọmọdé. Bẹ́ẹ̀ ni, Baba, torí pé ohun tí o fọwọ́ sí nìyí.+

  • 1 Kọ́ríńtì 1:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 àmọ́, Ọlọ́run yan àwọn ohun òmùgọ̀ ayé, kí ó lè dójú ti àwọn ọlọ́gbọ́n; Ọlọ́run sì yan àwọn ohun aláìlera ayé, kí ó lè dójú ti àwọn ohun tó lágbára;+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́