Máàkù 2:27, 28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ó wá sọ fún wọn pé: “A dá Sábáàtì torí èèyàn,+ a ò dá èèyàn torí Sábáàtì. 28 Torí náà, Ọmọ èèyàn ni Olúwa, àní Olúwa Sábáàtì.”+ Lúùkù 6:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó wá sọ fún wọn pé: “Ọmọ èèyàn ni Olúwa Sábáàtì.”+
27 Ó wá sọ fún wọn pé: “A dá Sábáàtì torí èèyàn,+ a ò dá èèyàn torí Sábáàtì. 28 Torí náà, Ọmọ èèyàn ni Olúwa, àní Olúwa Sábáàtì.”+