Mátíù 13:38, 39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 ayé ni pápá náà.+ Ní ti irúgbìn tó dáa, àwọn yìí ni àwọn ọmọ Ìjọba náà, àmọ́ àwọn ọmọ ẹni burúkú náà ni èpò,+ 39 Èṣù sì ni ọ̀tá tó gbìn wọ́n. Ìparí ètò àwọn nǹkan* ni ìgbà ìkórè, àwọn áńgẹ́lì sì ni olùkórè.
38 ayé ni pápá náà.+ Ní ti irúgbìn tó dáa, àwọn yìí ni àwọn ọmọ Ìjọba náà, àmọ́ àwọn ọmọ ẹni burúkú náà ni èpò,+ 39 Èṣù sì ni ọ̀tá tó gbìn wọ́n. Ìparí ètò àwọn nǹkan* ni ìgbà ìkórè, àwọn áńgẹ́lì sì ni olùkórè.