Mátíù 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ṣùgbọ́n lẹ́yìn tó fara balẹ̀ ro ọ̀rọ̀ yìí, wò ó! áńgẹ́lì Jèhófà* fara hàn án lójú àlá, ó sọ pé: “Jósẹ́fù, ọmọ Dáfídì, má bẹ̀rù láti mú Màríà ìyàwó rẹ lọ sílé, torí oyún inú rẹ̀* jẹ́ nípasẹ̀ ẹ̀mí mímọ́.+
20 Ṣùgbọ́n lẹ́yìn tó fara balẹ̀ ro ọ̀rọ̀ yìí, wò ó! áńgẹ́lì Jèhófà* fara hàn án lójú àlá, ó sọ pé: “Jósẹ́fù, ọmọ Dáfídì, má bẹ̀rù láti mú Màríà ìyàwó rẹ lọ sílé, torí oyún inú rẹ̀* jẹ́ nípasẹ̀ ẹ̀mí mímọ́.+