Máàkù 7:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ó gbéra níbẹ̀, ó sì lọ sí agbègbè Tírè àti Sídónì.+ Ó wọ ilé kan níbẹ̀, kò sì fẹ́ kí ẹnikẹ́ni mọ̀ nípa rẹ̀, síbẹ̀ àwọn èèyàn mọ̀.
24 Ó gbéra níbẹ̀, ó sì lọ sí agbègbè Tírè àti Sídónì.+ Ó wọ ilé kan níbẹ̀, kò sì fẹ́ kí ẹnikẹ́ni mọ̀ nípa rẹ̀, síbẹ̀ àwọn èèyàn mọ̀.