Máàkù 8:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Wọ́n sì jẹ, wọ́n yó, ohun tó ṣẹ́ kù tí wọ́n kó jọ sì kún apẹ̀rẹ̀ ńlá* méje.+ 9 Nǹkan bí ẹgbẹ̀rún mẹ́rin (4,000) ọkùnrin ló wà níbẹ̀. Lẹ́yìn náà, ó ní kí wọ́n máa lọ.
8 Wọ́n sì jẹ, wọ́n yó, ohun tó ṣẹ́ kù tí wọ́n kó jọ sì kún apẹ̀rẹ̀ ńlá* méje.+ 9 Nǹkan bí ẹgbẹ̀rún mẹ́rin (4,000) ọkùnrin ló wà níbẹ̀. Lẹ́yìn náà, ó ní kí wọ́n máa lọ.