-
Lúùkù 9:44, 45Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
44 “Ẹ fetí sílẹ̀ dáadáa, kí ẹ sì máa rántí àwọn ọ̀rọ̀ yìí, torí a máa fi Ọmọ èèyàn lé àwọn èèyàn lọ́wọ́.”+ 45 Àmọ́ ohun tó ń sọ kò yé wọn. Ní tòótọ́, a fi pa mọ́ fún wọn kó má bàa yé wọn, ẹ̀rù sì ń bà wọ́n láti bi í nípa ọ̀rọ̀ yìí.
-