1 Kọ́ríńtì 10:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ẹ máa ṣọ́ra kí ẹ má bàa di ohun ìkọ̀sẹ̀ fún àwọn Júù àti àwọn Gíríìkì àti fún ìjọ Ọlọ́run,+ 2 Kọ́ríńtì 6:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 A ò ṣe ohun tó lè fa ìkọ̀sẹ̀ lọ́nàkọnà, kí iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa má bàa ní àbùkù;+