Máàkù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Bí a ṣe kọ ọ́ sínú ìwé wòlíì Àìsáyà pé: “(Wò ó! Màá rán ìránṣẹ́ mi ṣáájú rẹ,* ẹni tó máa ṣètò ọ̀nà rẹ.)+ Jòhánù 1:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ó sọ pé: “Èmi ni ohùn ẹni tó ń ké nínú aginjù pé, ‘Ẹ mú ọ̀nà Jèhófà* tọ́,’+ bí wòlíì Àìsáyà ṣe sọ.”+
2 Bí a ṣe kọ ọ́ sínú ìwé wòlíì Àìsáyà pé: “(Wò ó! Màá rán ìránṣẹ́ mi ṣáájú rẹ,* ẹni tó máa ṣètò ọ̀nà rẹ.)+
23 Ó sọ pé: “Èmi ni ohùn ẹni tó ń ké nínú aginjù pé, ‘Ẹ mú ọ̀nà Jèhófà* tọ́,’+ bí wòlíì Àìsáyà ṣe sọ.”+