11 Ṣùgbọ́n ní báyìí mò ń kọ̀wé sí yín pé kí ẹ jáwọ́ nínú kíkẹ́gbẹ́+ pẹ̀lú ẹnikẹ́ni tí a pè ní arákùnrin, àmọ́ tó jẹ́ oníṣekúṣe tàbí olójúkòkòrò+ tàbí abọ̀rìṣà tàbí pẹ̀gànpẹ̀gàn tàbí ọ̀mùtípara+ tàbí alọ́nilọ́wọ́gbà,+ kí ẹ má tiẹ̀ bá irú ẹni bẹ́ẹ̀ jẹun.