Rúùtù 4:18-22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ìlà ìdílé* Pérésì+ nìyí: Pérésì bí Hésírónì;+ 19 Hésírónì bí Rámù; Rámù bí Ámínádábù;+ 20 Ámínádábù+ bí Náṣónì; Náṣónì bí Sálímọ́nì; 21 Sálímọ́nì bí Bóásì; Bóásì bí Óbédì; 22 Óbédì bí Jésè;+ Jésè sì bí Dáfídì.+
18 Ìlà ìdílé* Pérésì+ nìyí: Pérésì bí Hésírónì;+ 19 Hésírónì bí Rámù; Rámù bí Ámínádábù;+ 20 Ámínádábù+ bí Náṣónì; Náṣónì bí Sálímọ́nì; 21 Sálímọ́nì bí Bóásì; Bóásì bí Óbédì; 22 Óbédì bí Jésè;+ Jésè sì bí Dáfídì.+