Máàkù 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jòhánù wọ aṣọ tí wọ́n fi irun ràkúnmí ṣe, ó sì de àmùrè tí wọ́n fi awọ ṣe mọ́ ìbàdí rẹ̀,+ ó máa ń jẹ eéṣú àti oyin ìgàn.+
6 Jòhánù wọ aṣọ tí wọ́n fi irun ràkúnmí ṣe, ó sì de àmùrè tí wọ́n fi awọ ṣe mọ́ ìbàdí rẹ̀,+ ó máa ń jẹ eéṣú àti oyin ìgàn.+