Àìsáyà 62:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ wò ó! Jèhófà ti kéde títí dé àwọn ìkángun ayé pé: “Ẹ sọ fún ọmọbìnrin Síónì pé,‘Wò ó! Ìgbàlà rẹ ń bọ̀.+ Wò ó! Èrè rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀,Ẹ̀san rẹ̀ sì wà níwájú rẹ̀.’”+ Jòhánù 12:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Má bẹ̀rù, ọmọbìnrin Síónì. Wò ó! Ọba rẹ ń bọ̀, ó jókòó sórí ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.”*+
11 Ẹ wò ó! Jèhófà ti kéde títí dé àwọn ìkángun ayé pé: “Ẹ sọ fún ọmọbìnrin Síónì pé,‘Wò ó! Ìgbàlà rẹ ń bọ̀.+ Wò ó! Èrè rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀,Ẹ̀san rẹ̀ sì wà níwájú rẹ̀.’”+