Máàkù 11:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àwọn tó ń lọ níwájú àti àwọn tó ń bọ̀ lẹ́yìn sì ń kígbe ṣáá pé: “A bẹ̀ ọ́, gbà là!+ Ìbùkún ni fún ẹni tó ń bọ̀ ní orúkọ Jèhófà!*+ 10 Ìbùkún ni fún Ìjọba Dáfídì bàbá wa tó ń bọ̀!+ A bẹ̀ ọ́, gbà là, ní ibi gíga lókè!”
9 Àwọn tó ń lọ níwájú àti àwọn tó ń bọ̀ lẹ́yìn sì ń kígbe ṣáá pé: “A bẹ̀ ọ́, gbà là!+ Ìbùkún ni fún ẹni tó ń bọ̀ ní orúkọ Jèhófà!*+ 10 Ìbùkún ni fún Ìjọba Dáfídì bàbá wa tó ń bọ̀!+ A bẹ̀ ọ́, gbà là, ní ibi gíga lókè!”