Ìṣe 19:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Pọ́ọ̀lù sọ pé: “Ìrìbọmi tí Jòhánù ṣe fún àwọn èèyàn jẹ́ àmì ìrònúpìwàdà,+ ó ń sọ fún wọn pé kí wọ́n gba ẹni tó ń bọ̀ lẹ́yìn òun gbọ́,+ ìyẹn Jésù.”
4 Pọ́ọ̀lù sọ pé: “Ìrìbọmi tí Jòhánù ṣe fún àwọn èèyàn jẹ́ àmì ìrònúpìwàdà,+ ó ń sọ fún wọn pé kí wọ́n gba ẹni tó ń bọ̀ lẹ́yìn òun gbọ́,+ ìyẹn Jésù.”