ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Lúùkù 20:37, 38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 Àmọ́ tó bá kan àjíǹde àwọn òkú, Mósè pàápàá jẹ́ ká mọ̀ nínú ìtàn igi ẹlẹ́gùn-ún, nígbà tó pe Jèhófà* ní ‘Ọlọ́run Ábúráhámù, Ọlọ́run Ísákì àti Ọlọ́run Jékọ́bù.’+ 38 Kì í ṣe Ọlọ́run àwọn òkú, àmọ́ ó jẹ́ Ọlọ́run àwọn alààyè, torí lójú rẹ̀,* gbogbo wọn wà láàyè.”+

  • Róòmù 4:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 (Èyí bá ohun tó wà lákọsílẹ̀ mu pé: “Mo ti yàn ọ́ ṣe bàbá ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè.”)+ Èyí jẹ́ lójú Ọlọ́run, ẹni tó ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀, tó ń sọ òkú di ààyè, tó sì ń pe àwọn ohun tí kò sí bíi pé wọ́n wà.*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́