Máàkù 12:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ọ̀kan nínú àwọn akọ̀wé òfin tó wá, tó gbọ́ tí wọ́n ń fa ọ̀rọ̀, tó sì mọ̀ pé ó ti dá wọn lóhùn lọ́nà tó dáa, bi í pé: “Èwo ni àkọ́kọ́* nínú gbogbo àṣẹ?”+
28 Ọ̀kan nínú àwọn akọ̀wé òfin tó wá, tó gbọ́ tí wọ́n ń fa ọ̀rọ̀, tó sì mọ̀ pé ó ti dá wọn lóhùn lọ́nà tó dáa, bi í pé: “Èwo ni àkọ́kọ́* nínú gbogbo àṣẹ?”+