Lúùkù 11:52 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 52 “Ẹ gbé, ẹ̀yin tí ẹ mọ Òfin dunjú, torí ẹ mú kọ́kọ́rọ́ ìmọ̀ lọ. Ẹ̀yin fúnra yín ò wọlé, ẹ sì ń dí àwọn tó ń wọlé lọ́wọ́!”+
52 “Ẹ gbé, ẹ̀yin tí ẹ mọ Òfin dunjú, torí ẹ mú kọ́kọ́rọ́ ìmọ̀ lọ. Ẹ̀yin fúnra yín ò wọlé, ẹ sì ń dí àwọn tó ń wọlé lọ́wọ́!”+