-
Lúùkù 21:21-23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Kí àwọn tó wà ní Jùdíà bẹ̀rẹ̀ sí í sá lọ sí àwọn òkè,+ kí àwọn tó wà nínú ìlú náà kúrò níbẹ̀, kí àwọn tó sì wà ní ìgbèríko má wọ ibẹ̀, 22 torí pé àwọn ọjọ́ yìí la máa ṣe ìdájọ́,* kí gbogbo ohun tí a kọ lè ṣẹ. 23 Ó mà ṣe o, fún àwọn aláboyún àti àwọn tó ń tọ́ ọmọ jòjòló ní àwọn ọjọ́ yẹn o!+ Torí wàhálà ńlá máa bá ilẹ̀ náà, ìbínú sì máa wá sórí àwọn èèyàn yìí.
-