Lúùkù 17:26, 27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Bákan náà, bó ṣe rí gẹ́lẹ́ ní àwọn ọjọ́ Nóà,+ bẹ́ẹ̀ ló ṣe máa rí ní àwọn ọjọ́ Ọmọ èèyàn:+ 27 wọ́n ń jẹ, wọ́n ń mu, àwọn ọkùnrin ń gbéyàwó, à ń fa àwọn obìnrin fún ọkọ, títí di ọjọ́ tí Nóà wọ ọkọ̀ áàkì,+ Ìkún Omi sì dé, ó pa gbogbo wọn run.+
26 Bákan náà, bó ṣe rí gẹ́lẹ́ ní àwọn ọjọ́ Nóà,+ bẹ́ẹ̀ ló ṣe máa rí ní àwọn ọjọ́ Ọmọ èèyàn:+ 27 wọ́n ń jẹ, wọ́n ń mu, àwọn ọkùnrin ń gbéyàwó, à ń fa àwọn obìnrin fún ọkọ, títí di ọjọ́ tí Nóà wọ ọkọ̀ áàkì,+ Ìkún Omi sì dé, ó pa gbogbo wọn run.+