Ìfihàn 19:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó wá sọ fún mi pé, “Kọ̀wé pé: Aláyọ̀ ni àwọn tí a pè wá síbi oúnjẹ alẹ́ ìgbéyàwó Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà.”+ Bákan náà, ó sọ fún mi pé: “Àwọn ọ̀rọ̀ tòótọ́ tí Ọlọ́run sọ nìyí.”
9 Ó wá sọ fún mi pé, “Kọ̀wé pé: Aláyọ̀ ni àwọn tí a pè wá síbi oúnjẹ alẹ́ ìgbéyàwó Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà.”+ Bákan náà, ó sọ fún mi pé: “Àwọn ọ̀rọ̀ tòótọ́ tí Ọlọ́run sọ nìyí.”