1 Tẹsalóníkà 5:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí náà, ẹ má ṣe jẹ́ kí a máa sùn bí àwọn yòókù ti ń ṣe,+ àmọ́ ẹ jẹ́ kí a wà lójúfò,+ kí a sì máa ronú bó ṣe tọ́.+ 1 Pétérù 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹ máa ronú bó ṣe tọ́, ẹ wà lójúfò!+ Èṣù tó jẹ́ ọ̀tá yín ń rìn káàkiri bíi kìnnìún tó ń ké ramúramù, ó ń wá bó ṣe máa pani jẹ.*+
6 Torí náà, ẹ má ṣe jẹ́ kí a máa sùn bí àwọn yòókù ti ń ṣe,+ àmọ́ ẹ jẹ́ kí a wà lójúfò,+ kí a sì máa ronú bó ṣe tọ́.+
8 Ẹ máa ronú bó ṣe tọ́, ẹ wà lójúfò!+ Èṣù tó jẹ́ ọ̀tá yín ń rìn káàkiri bíi kìnnìún tó ń ké ramúramù, ó ń wá bó ṣe máa pani jẹ.*+