Lúùkù 19:16, 17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Èyí àkọ́kọ́ wá bá a, ó sọ pé, ‘Olúwa, mo fi mínà rẹ jèrè mínà mẹ́wàá.’+ 17 Ó sọ fún un pé, ‘O káre láé, ẹrú rere! Torí o ti fi hàn pé o jẹ́ olóòótọ́ nínú ohun tó kéré gan-an, jẹ́ aláṣẹ lórí ìlú mẹ́wàá.’+
16 Èyí àkọ́kọ́ wá bá a, ó sọ pé, ‘Olúwa, mo fi mínà rẹ jèrè mínà mẹ́wàá.’+ 17 Ó sọ fún un pé, ‘O káre láé, ẹrú rere! Torí o ti fi hàn pé o jẹ́ olóòótọ́ nínú ohun tó kéré gan-an, jẹ́ aláṣẹ lórí ìlú mẹ́wàá.’+