Hébérù 12:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 bí a ṣe ń tẹjú mọ́ Jésù, Olórí Aṣojú àti Aláṣepé ìgbàgbọ́ wa.+ Torí ayọ̀ tó wà níwájú rẹ̀, ó fara da òpó igi oró,* kò ka ìtìjú sí, ó sì ti jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún ìtẹ́ Ọlọ́run.+
2 bí a ṣe ń tẹjú mọ́ Jésù, Olórí Aṣojú àti Aláṣepé ìgbàgbọ́ wa.+ Torí ayọ̀ tó wà níwájú rẹ̀, ó fara da òpó igi oró,* kò ka ìtìjú sí, ó sì ti jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún ìtẹ́ Ọlọ́run.+