8 Torí ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, lẹ́yìn tí a ti yìn ín lógo, ó rán mi sí àwọn orílẹ̀-èdè tó ń kó ẹrù yín,+ pé; ‘Ẹni tó bá fọwọ́ kàn yín ń fọwọ́ kan ẹyinjú* mi.+
4 ó ṣubú lulẹ̀, ó sì gbọ́ tí ohùn kan sọ fún un pé: “Sọ́ọ̀lù, Sọ́ọ̀lù, kí nìdí tí o fi ń ṣe inúnibíni sí mi?” 5 Ó béèrè pé: “Ta ni ọ́, Olúwa?” Ó sọ pé: “Èmi ni Jésù,+ ẹni tí ò ń ṣe inúnibíni sí.+