Mátíù 26:57 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 57 Àwọn tó mú Jésù wá mú un lọ sọ́dọ̀ Káyáfà+ tó jẹ́ àlùfáà àgbà, níbi tí àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn àgbààgbà kóra jọ sí.+ Lúùkù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 nígbà ayé Ánásì olórí àlùfáà àti Káyáfà,+ Jòhánù+ ọmọ Sekaráyà gbọ́ ìkéde látọ̀dọ̀ Ọlọ́run nínú aginjù.+ Jòhánù 11:49 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 Àmọ́ ọ̀kan lára wọn, Káyáfà,+ tó jẹ́ àlùfáà àgbà lọ́dún yẹn sọ fún wọn pé: “Ẹ ò mọ nǹkan kan rárá, Jòhánù 18:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wọ́n kọ́kọ́ mú un lọ sọ́dọ̀ Ánásì, torí òun ni bàbá ìyàwó Káyáfà,+ tó jẹ́ àlùfáà àgbà lọ́dún yẹn.+ Jòhánù 18:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ánásì wá dè é, ó sì ní kí wọ́n mú un lọ sọ́dọ̀ Káyáfà àlùfáà àgbà.+
57 Àwọn tó mú Jésù wá mú un lọ sọ́dọ̀ Káyáfà+ tó jẹ́ àlùfáà àgbà, níbi tí àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn àgbààgbà kóra jọ sí.+
2 nígbà ayé Ánásì olórí àlùfáà àti Káyáfà,+ Jòhánù+ ọmọ Sekaráyà gbọ́ ìkéde látọ̀dọ̀ Ọlọ́run nínú aginjù.+
49 Àmọ́ ọ̀kan lára wọn, Káyáfà,+ tó jẹ́ àlùfáà àgbà lọ́dún yẹn sọ fún wọn pé: “Ẹ ò mọ nǹkan kan rárá,
13 Wọ́n kọ́kọ́ mú un lọ sọ́dọ̀ Ánásì, torí òun ni bàbá ìyàwó Káyáfà,+ tó jẹ́ àlùfáà àgbà lọ́dún yẹn.+