Máàkù 14:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ó ṣe ohun tó lè ṣe; ó da òróró onílọ́fínńdà sí ara mi ṣáájú nítorí ìsìnkú.+ Jòhánù 12:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Torí náà, Jésù sọ pé: “Fi í sílẹ̀, kó lè ṣe èyí nítorí ọjọ́ ìsìnkú mi.+