Jòhánù 18:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Lẹ́yìn tó sọ àwọn nǹkan yìí, Jésù àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ lọ sí òdìkejì Àfonífojì Kídírónì,*+ níbi tí ọgbà kan wà, òun àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ sì wọnú ibẹ̀.+
18 Lẹ́yìn tó sọ àwọn nǹkan yìí, Jésù àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ lọ sí òdìkejì Àfonífojì Kídírónì,*+ níbi tí ọgbà kan wà, òun àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ sì wọnú ibẹ̀.+