Mátíù 6:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Kí Ìjọba rẹ dé.+ Kí ìfẹ́ rẹ+ ṣẹ ní ayé,+ bíi ti ọ̀run. Jòhánù 12:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ní báyìí, ìdààmú bá mi,*+ kí sì ni kí n sọ? Baba, gbà mí kúrò nínú wákàtí yìí.+ Síbẹ̀, torí èyí ni mo fi wá sí wákàtí yìí.
27 Ní báyìí, ìdààmú bá mi,*+ kí sì ni kí n sọ? Baba, gbà mí kúrò nínú wákàtí yìí.+ Síbẹ̀, torí èyí ni mo fi wá sí wákàtí yìí.